Samson to gun ore e pa l`Ota so pe inu lo si oun bi
Transcripción
Samson to gun ore e pa l`Ota so pe inu lo si oun bi
E ba wa dele E mo nipa wa ba wa sise Adiresi wa E polowo oja yin AKEDE Agbaye Idanileko ALAROYE Samson to gun ore e pa l'Ota so pe inu lo si oun bi Bi o ba fe Awon Iroyin to se koko Johnson Akinpelu, Abeokuta Owo tun te pasito mi-in O l'Ondo pelu oogun ·doômoôkunrin oômoô oôduôn meôeôeôdoôgboôn kan, Samson Teôlla, toôwoô awoôn oôloôpaa Ado-Odo O·ta teô loôseô to koôja pe o gun oôreô eô, Abdulkareem Abioôdun, pa ti jeôwoô pe loootoô loun huwa naa, o ni inu lo sôi oun bi, oun ko si moô pe ibi to maa ja si niyeôn. O soôroô yii lakooko to n sôalaye idi to fi ran oôreô eô loôrun airoteôleô, o ni loootoô oôreô lawoôn, tawoôn si ti n ba ara boô tipeô, sôugboôn esôu lo ya awoôn mejeeji lo to fi di pe oun gbeômi eô. Loôjoô Isôeôgun, Tusde, oôseô to koôja lawoôn oôloôpaa mu Samson ni Iyeôsi-O·ta lori eôsun pe o gun oôreô eô nigo laya nigba tija waye laarin awoôn mejeeji lori oôroô ti ko nitumoô to sôeôleô laarin woôn. Geôgeô bi Samson sôe soô nigba to n ba akoôroyin wa soôroô, o ni ki i sôe Abdulkareem lo yeô ki iku eô toôwoô oun wa, nitori oun ati eô sunmoô ara woôn gidi, sôugboôn esôu lo ba faaji awoôn jeô to fi di pe o toôwoô oun ku. Koômisôanna awoôn oôloôpaa nipinleô Ogun, Abdul Majid Ali, ti soô pe iwadii sôi n loô loôwoô, beôeô lo ni Samson n foôwoô sowoô poô peôlu awoôn, yoo si foju bale-eôjoô laipeô. O waa roô awoôn eeyan ti woôn maa n binu abisodi pe ki woôn roôra maa sôe, nitori ibi to maa n yoôri si ki i dara. Beôeô lo tun roô awoôn oôdoô lati sôoôra fun iwa jagidijagan to le ko idaamu ba woôn. abenugongo Igbimo alakooso PDP pin si meji l'Ekiti, ileejo fofin de eyi ti Fayose yan Nitori awon Fulani, awon eeyan Oruntan rawo ebe sijoba l'Akure Eeyan meta ku ninu ija awon omo egbe okunkun n’Ibadan Ala ti aafaa la ti so o dero ewon n'Ilorin Owo te ayederu agbejoro l'Ota E tun pade wa lori ero E wa awon iroyin wa