Iyaale mi ti tun bere o, o fere bu mi pa

Transcripción

Iyaale mi ti tun bere o, o fere bu mi pa
E ba wa dele
E mo nipa wa
E polowo oja yin
AKEDE Agbaye
Idanileko ALAROYE
Bi o ba fe ba wa sise
Iyaale mi ti tun bere o, o fere bu mi pa
Adiresi wa
Awon Iroyin to se koko
Wahala nla ninu egbe
A
oselu ACN l’Ondo
WON› ore ô Iya Dele ti ko ba a. Sôeôe eô moô pe awoôn oôreô woônyi, O·loôuôun lo n kooyan yoô
loôwôo woôn, awoôn oôreô orisôiirisiôi ni woôn deô wa laye, awoôn oôôreô ti woôn maa n sôi ara woôn loôna
loô poô ninu awoôn oôreô aye ode-oni yii. Nitori eô lemi sôe n soôra, mo n soôra mi gan-an o. Mi o
loôrôeô,ô, mi o loôta, jeôjeô mi ni mo n loô.ô. Mi o feô keônôni kan fi tieô ko ba temi.
Bi eô ba moô bi Iya Dele sôe sôe loôjoô ti dokita soô fun un pe o ko atoôsi yii, eôyin naa ti maa moô
pe nnkan mi-in wa nibeô. Bo ba jeô oôkoô eô lo ko atoôsi ran an, kin ni wahala ti yoo ba a ti yoo
si tori eô maa daro bii eôni ti oômoô ku loôwoô reô. Sôugboôn, awoôn oôroô ti Iya Dele n soô loôjoô naa fi
han pe o ti ko atoôsi naa ran oôkunrin kan, tabi meji, ohun to jeô ki wahala ba a gan-an niyeôn.
Ko jeôwoô fun mi o, ko jeôwoô fun mi rara. Sôugboôn mo moô. Mo moô daadaa paapaa. Bo sôe n
soôroô lo jeô ki n moô, mo moô pe nnkan kan wa nidii oôroô yii to jeô Iya Dele funra eô lo le soô.
Dokita soô pe o ko atoôsi, iyeôn deô soô pe ki i sôe arun kan to le rara, paapaa nitori atoôsi iru kan
naa to wa lara oôkoô eô lo wa lara eô, iyeôn deô fi han pe oôkoô lo ko o ran an, oogun kan naa ti
oun deô feôeô lo foôkoô eô naa loun maa lo fun un.
Eô gboô, ki lo waa
yeô ko di wahala ninu iyeôn@
Ki lo yeô ko fa
idaro reôpeôteô, ki lo yeô ko fa
ki ara maa gbona
bii ki iba maa sôeeyan@
Nnkan mi-in wa
nibeô ni. Bi dokita sôe soôroô
fun un tan beôeô
yeôn, nisôe lo gbe baagi eô, ni
mo ba n le e loô,
abi nigba ti ko duro de mi.
Ki n too jaja ba a
loôna ti mo si soô fun un pe o
yeô ko gba oogun
ati abeôreô loôwoô dokita ko le
loôoô lo o nile ki
oun to n sôe e le loô, nisôe lo
taku, o ni oun ko
le gba oogun kankan beôeô
yeôn, o ni ori oun Iya Biola
ko pe rara, oun ko moô bo
sôe n sôe oun, ara
oun n gbona, ori oun feôeô
daru. Ni mo ba ni o daa nigba yeôn, ko loô si sôoôoôbu eô ko loôoô sinmi, bo ba deô sinmi tan ti ara
reô ba baleô, yoo moô ohun ti yoo sôe nigba naa. O loun o loô si sôoôoôbu oun, o ni sôoôoôbu mi loun
feôeô loô. Mo si ni o daa, ko jeô ka loô.
Sôugboôn bi a ti n loô loôna lo n pariwo, beôeô lo n daro. Iru kin ni mo ko yii! Iru kin ni Baba
Dele ko ba mi yii! Iru abuku wo loôkunrin yii feôeô fi kan mi laarin awoôn eôgbeô mi yii! Nibeô
ni mo ti soô fun un pe, Ki lo kan awoôn eôgbeô yin ninu eleyii, sôe eôyin feôeô loôoô soô fun woôn ni!
Esi ti Iyaale mi fun mi ba mi leôru, o ni, Woôn maa moô!
Nisôe ni mo n ronu oôroô naa titi. Woôn maa moô, woôn maa moô. Bawo ni woôn sôe feôeô moô. Igba
ti ko ye mi ni mo tun bi i pe, Bawo ni woôn sôe feôeô moô, lo ba ni, Nnkan to maa jeô ki woôn
moô wa nibeô, woôn maa moô sôaa ni! Igba naa loôroô naa ja mi ninu, asôiri maa tu nigba ti ale eô
ba waa feôjoô eô sun pe o ko atoôsi ran oun.
Awoôn oôreô Iya Dele ti ba a wa ale kan. Mo moô pe Iya Dele ti ni tieô loôwoô teôleô o, sôugboôn
nigba ti Alaaji ko ba ti da a lohun lo maa n jade sita, bi oôkoô wa ba ti n da a lohun daadaa,
ti woôn joô n pade, ko ni i wo ita rara. Ki i kuku sôe owo lo feôran lara oôkunrin, o kan feôran ki
woôn maa ba oun sun lasan ni. Bi Alaaji ba si ti n sôe eyi fun un, ki i wo oju eôlomin-in nita
rara. Sôugboôn ti asiko yii yato, nitori Alaaji n sun moô oôn daadaa ko too di olowo ojiji yii.
Ohun ti mo sôe moô pe awoôn oôreô eô lo ko ba a niyeôn. Bo sôe n loô si sôoôoôbu mi lo dorikodo, bo
si sôe doôhun-un, nisôe lo wo lu sôia kan nibeô, ti gbogbo oju eô poôn nibi to ti n sunkun. Haa,
aye mi ti bajeô, kin ni mo feôeô maa soô ti asôiri ba tu bayii, bawo ni mo sôe feôeô sôe e, eôni-eôleôni.
Bawo ni mo sôe maa ko temi ran eôni ti ko moôwoô ti ko meôseô. Bawo ni mo sôe maa sôe nigba ti
asôiri ba tu bayii.
Saka Lawal, Olaiya Oni,
Boroface atawon mi-in
darapo mo egbe PDP
Ta lo ba wa ri i o: Rasaq
Gawat, agbalagba
sorosoro ori telifisan
jade nile ko ti i pada wale
o
Bale ile yii ma ti jewo, o
ni: Loooto ni mo pa
iyawo mi nitori o n yan
ale
Nitori bo se mu eto ogbin
ni pataki, Minisita
gbosuba fun Gomina
Fasola
Ibo ijoba ibile ipinle
Ogun ku si dede: Awon
omo egbe ACN n darapo
mo egbe oselu mi-in
Ara kan ma tun ree!
Lasiko ti eto igbeyawo n
lo lowo ni Silifatu taku, o
loun ko fe oko oun mo
E tun pade wa lori ero
E wa awon iroyin wa
Iyeôn lo jeô ki emi beere loôwoô eô o. Iyaale mi, sôe eô ti ko atoôsi ran eôni kan ni@ Ko da mi lohun
o, ni mo ba tun beere. Iyaale mi, ta leô ko atoôsi ran seô@ Nisôe ni Iya Dele ma binu> Ta ni mo
soô fun eô pe mo ko atoôsi ran! Ki lo kan eô kan aye mi! Sôe iwoô niyaa mi ni abi iwoô ni baba mi!
Ma da si oôroô mi moô o! Soôgaba eô o, Iya ile-oôoôkan.
Solo-Makinde, Gbeboorun! Iya Dele ko ma dakeô, o n bu mi loô ni!

Documentos relacionados