Iya Dele ma n korin owe bu mi ninu ile o
Transcripción
Iya Dele ma n korin owe bu mi ninu ile o
E ba wa dele E mo nipa wa E polowo oja yin AKEDE Agbaye Idanileko ALAROYE Bi o ba fe ba wa sise Adiresi wa Iya Dele ma n korin owe bu mi ninu ile o Awon Iroyin to se koko O·LO›UN ni ko gba mi o, ko sôoô mi ninu ija orogun o. Bi eeyan ba loun ko ni i ja, to Adajo da oga awon PDP ba loun ko ni i soôroô, nigba ti woôn ba n foôboô loô oô bayii nkoô. Sôugboôn woôn ti soô fun mi pe ki n ma ja, woônô ti soô pe ija nla kan wa niwaju mi, ki n ma ja o, ki n sôa maa woran, ki n jeô ki suuru mi poô daadaa, woôn ni bo ba peô bo ba ya, Oôloôun a sôeôgun fun mi, emi naa yoo foju ara mi ri i bayii. Oôroô temi ma n soô yii ki i sôere o. Ki i sôere rara. Bi gbogbo wahala oôroô moôto ko sôe moôto ti beôreô nile wa yii, emi ki peô ki n to kuro nile, ko to di aago meôjoô mo ti wa ni sôoôoôbu mi, idi isôeô eôni la sôa ti n moô ni loôleô. N o tieô feô kawoôn oôroô reôdeôreôdeô ti woôn joô n fa nibeô yeôn maa sôoju mi, mo maa n feôeô rin jinna si sakaani woôn ni. Bi mo sôe n rin loô si sôoôoôbu laaaroô oôjoô yii, sôe ki i sôe gbogbo igba ni mo n gbe moôto loô, abi irin isôeôju meloo nile wa sinu oôja Osôodi, eeyan ko kuku tieô ni i ribi gbe moôto naa si, oôpoô igba lo jeô pe ti a ba gbe moôto loô, iwaju sôoôoôbu nibeô la maa gbe e si, to tun maa maa di awoôn koôsitoôma loôwoô. Ohun temi ki i sôee fi Iya Biola gbogbo igba gbe moôto loô niyi. Eôseô mi ni mo fi n rin. Bi mo sôe n rin faufau loô nijoô naa, beôeô ni mo gboô gboôngan leôyin mi, awoôn aladura ti woôn maa n lu aago kiri yeôn ni. Leôeôkoôoôkan beôeô, bi mo ba ti pade woôn, mo maa n fun woôn lowo. Eeyan n sôubu to n da¯ya¯ de;leô̄, ka ma ti i soô pe ka doôbaleô ka ki a¯na eôni. Eelo ni mo feôeô fun woôn, sôebi kadura eeyan sôa gba nibi oore to ba n sôe, oore keekeekee beôeô maa n jeô keômi eeyan gun ni. Ohun ti ko jeô ka;ya¯ mi ja nigba ti mo gboô aago aladura yeôn niyi, ni mo ba boju weôyin, mo ri i to n sôeôwoô si mi. Ni mo ba duro, lo ba rin ba mi, o ni o ti peô toun ti n pe mi, n ko gboô ni. A¯ya¯ mi ko kuku ja, mo ti moô pe laarin Osôodi yii, lojumoômoô bayii, ko seôni to jeô ba mi dan iranu kan wo, awoôn oômo Osôodi lo maa lu u pa. N ko si wa owo ojiji, eeyan kan ko le tan mi si koôroô ko loun feôeô sôoogun owo fun mi. Iyeôn ni mo sôe duro ti mo beere pe sôe ko si nnkan o. O ni ko si nnkan, o leômi-in oôrun ran oun si mi ni. Ni mo ba ni ko maa jisôeô eô. O loun gboô, ohun kan naa to soô fun mi ni pe, ija nla n bo nile wa o, awoôn kan maa wa mi nija, woôn maa toô mi daadaa, sôugboôn ki n ti mura eô sileô, ki n ti moô pe isôeô esôu ni o, woôn feôeô fi soô mi leônu ni o, ki n ma da si i rara, ki n ni suuru, emi naa yoo ri nigba toôroô O·loôun ba n sôeô. Mo duro pe ko maa boôroô eô loô, lo ba ni ko soôroô kankan moô, o ni iba ohun ti woôn ni koun soô fun mi niyeôn. Ni mo ba dupeô loôwoô eô, nitori ti ko si soô pe ki n wa sôe nnkan kan, tabi ki n mu owo kan wa, mo toôwoô boô apo pe ki n fun un lowo, sôugboôn oôkunrin naa taku, lo ba n rin loô kemoô-kemoô, lo n lu aago bo ti n loô, o loun ko gboôdoô gba owo kankan loôwoô mi loôjoô naa, nitori a ko fi ran oun lati gbowo. N’Ijebu-Ode, awon pada sewon l’Osogbo olopaa tun n gbegi dina O ma se o! Awon olopaa yinbon pa olori egbe OPC l’Ondo Ojubo kan ree o! Awon eeyan ni won fi n soogun owo “Baba mi n ba iyawo mi sun, n ko meni to lomo ninu awa mejeeji” Ipade apero waye lati fopin si wahala Boko Haraamu n’Ilorin E tun pade wa lori ero E wa awon iroyin wa Oôloôun n gboô nnkan ti mo n soô yii o, ko ma ju oôjoô keôta loô ti wahala sôeôleô nile wa loootoô. Ko sohun t’Iyaa Dele ko sôe fun mi tan o, dieô bayii lo ku ko fa mi lasôoô ya. Jeôjeô ni mo n loô si toôileôeôti laaaroô kutukutu, bi mo sôe beôreô si gboô orin leôyin mi niyeôn, Eô jeô ki n raaye sôe temi, eô ti sôe tiyin o, eô fun mi laaye ki n sôe temi. Emi o ba torogun waye, emi o ba torogun waye, eô ma feôjoô mi sunka, eô ma feôjoô mi sun eke, eô ma feôjoô mi sun eôni ti o feôran mi, n o ba torogun waye o. Iyeôn ni mo n ronu si pe iru orin wo ree laaaroô kutukutu, afi nigba ti mo tun n gboô, Kaluku lo ni tieô lara nibi to ba si, o¯fo¯ eeyan o ni i sôe eôlomi-in, eô gbeônu dani..., woôn n pe yin woôn feôeô raja, eô sôoôgba yin o. Eô sinmi galala, eô sôoôgba yin o, woôn ni eô waa foômoô ni fida, eô sôoôgba yin o. Anti agbeborun, eô sôoôgba yin o.... Sôe emi n’Iyaa Dele n koôrin owe bayii bu laaaroô kutukutu. Ohun ti mo n ro niyeôn o, afi bo sôe tun bu orin mi-in si i. Eô maa ka a loô loôseô to n boô.
Documentos relacionados
Samson to gun ore e pa l`Ota so pe inu lo si oun bi
eô nigo laya nigba tija waye laarin awoôn mejeeji lori oôroô ti ko nitumoô to sôeôleô laarin woôn. Geôgeô bi Samson sôe soô nigba to n ba akoôroyin wa soôroô, o ni ki i sôe Abdulkareem lo yeô ki ik...
Más detallesIyaale mi ti tun bere o, o fere bu mi pa
yeôn, o ni ori oun Iya Biola ko pe rara, oun ko moô bo sôe n sôe oun, ara oun n gbona, ori oun feôeô daru. Ni mo ba ni o daa nigba yeôn, ko loô si sôoôoôbu eô ko loôoô sinmi, bo ba deô sinmi tan ti...
Más detalles