Iya Biola Oniresi Loja Osodi Ninu Alaaji ati Iya Dele, eni

Transcripción

Iya Biola Oniresi Loja Osodi Ninu Alaaji ati Iya Dele, eni
E ba wa dele
E mo nipa wa
ba wa sise Adiresi wa
E polowo oja yin
AKEDE Agbaye
Idanileko ALAROYE
Iya Biola Oniresi Loja Osodi
Ninu Alaaji ati Iya Dele, eni kan ni yoo reyin enikan
O
Bi o ba fe
Awon Iroyin to se koko
Gomina Ekiti atawon
asofin e fee gbena woju
loôun nikan lo le sôaanu mi. Ohun ti mo ti ri bayii ni pe ki n sôa maa sôe daadaa, ki n ma
sôeka, ki n ma si jeô ki eônikeôni ti mi, nitori O·loôun to wa loke yeôn lo maa n gbeja mi. Bi eeyan
kan ba reô mi jeô, ti mi o ba ti binu, loju mi bayii ni O·loôun yoo si yanju oôroô naa fun mi. O·roô
emi ati Alaaji ni o, ohun to sôeôleô nile wa loôseô to koôja yii tun jeô ki n gba O·loôun O·ba gboô yatoô,
o tieô jeô keôru Oôloôun ba mi, nitori funra reô lo ko mi yoô.
Sôeô eô moô pe mo soô fun yin pe nigba ti Iya Dele kuro ni oôsibitu, nisôe lo taku pe oun ko ni i loô
sile, pe oun gboôdoô ri Alaaji, ti mo fi n beere loôwoô eô pe nibo ni yoo ti ri i, ti mo ba soô fun yin
pe ile mi tuntun ti Alaaji feôyawo si lo gba loô nkoô. Emi o le royin, Seôki lo le sôalaye ohun to
sôeôleô nibeô, nitori oun ni oômoôbinrin yeôn pada waa sôalaye fun, o loun ko le dojukoô mi, oju n ti
oun. Eô gboô, ewo ni temi ninu oôroô to wa nileô yii, emi koô loôkoô eô, emi si koô ni mo wa le e nile,
ohun ti woôn joô moô-oôn-jeô lo yo woôn.
Woôn ni nigba ti Iya Dele dele yeôn, to gbaleôkun gba gba gbaa, tobinrin yeôn sôileôkun bayii,
nisôe ni Iya Dele fi ara eô ha oju oôna, ni ileôkun ko ba sôee ti moô, lo ba taku sibeô, lo ba soô fun
obinrin yeôn pe oun yoo beôreô si i pariwo bayii, oun yoo si pariwo naa to jeô gbogbo ile ati
adugbo ni yoo beô jade, nigba naa loun yoo waa lu u daadaa loju gbogbo awoôn eeyan ti ko ba
pe Alaaji jade foun bayii bayii. Woôn ni obinrin Soyoyo yeôn ba n sôe meôn-in meôn-in, o feôeô
maa soô pe oun ko ri Alaaji latoôjoô yii, Iya Dele ko jeô ko soôroô jaleô, afi woi, woi, o gbe igbaju
fun un beôeô ni.
Bo sôe gbe igbaju fun un beôeô lo fariwo si i, “Araadugbo eô gba mi o, eô n wo mi niran ni!”
Woôn ni obinrin yeôn ko duro, ere buruku lo sa woônu ile, ko tieô ranti tileôkun, o fi ileôkun sileô
fun Iya Dele ni. Boya o ti ro pe iyaale mi yoo sare gba teôle oun ni, tabi ko jeô eôru lo ba a to
beôeô. Sôugboôn Iya Dele ko loô, nisôe lo duro seônu oôna nibeô, lo ba tun n pariwo, “Araadugbo eô
waa woran o”, beôeô lo gba ileôkun gbo gbo gbo, lo soô pe, “Jade o, ma sa woônu ile, jade o.”
O·toô ni eôni ti iyaale mi n reti, boya o ro pe obinrin yeôn n loôoô mura ija ni, afi bi toôhun sôe yoôju
si i ganboro, lo ba di Alaaji. Asôe inu ile yeôn ni Baba Bioôla wa. O ma ga o, awoôn oôkunrin ma
buru o, ki O·loôun ma maa gba wa loôwoô awoôn oôkoô wa yii ni o, bi woôn ba si ti ri obinrin tuntun
bayii, oôpoôloô woôn yoo si daru pata, woôn ko ni i moô ohun ti woôn n sôe moô, afigba ti woôn ba teô
nibeô, woôn yoo waa maa soô kantankantan, woôn le ni woôn loogun fawoôn ni. Iroô si ni o, ohun ti
woôn feôeô jeô nigba naa lo ko laakaye woôn loô, oogun kankan koô.
Seôki soô pe obinrin yeôn ni bi Alaaji ti yoô jade bayii, nisôe ni Iya Dele fo moô oôn loôrun, lo ba n
pariwo, “O o paayan leni-in o! Ajisôegiri, oo paayan leni-in o! Akanni, afi ko o lu mi pa leniin o! Bo o ba pa mi, baba reô koô lo bi oô, oo lu mi pa leni-in ni o. O fi mi soôsibitu, o gbagbe mi
sibeô, o waa sa wa soôdoô obinrin, o ba moôbeô, o n gbadun, iya n jeô emi, haaa, afi ko o pa mi
leni-in yii o.” Kia lo ti loô asôoô moô Alaaji loôrun, to n sôeeki eô, to fun asôoô moô oôn loôrun, loootoô
loootoô, nigba ti Alaaji naa si ri i boju eô sôe poôn ti ara eô n gboôn, gbogbo ibinu to wa ninu eô,
nisôe lo pareô.
Beôeô ni iyawo tuntun n beô eô, “Moômi eô sôe suuru, eô ma jeô ka feôdi ara wa sita, eô ma jeô kaye sôe
yeôyeô mi, eô dariji mi, emi o moô nnkan kan ninu gbogbo ohun ti eô n soô yii o, Dadi lo wa sibi ti
woôn ni awoôn feôeô sinmi, awoôn ko feô ki eôniboôdi distoôoôbu awoôn o, emi koô o, mi o moô kinni kan
nibeô o!” Woôn ni gbogbo bi obinrin yeôn sôe n beôbeô, Iya Dele ko wo oôdoô eô, ohun to n soô ni pe,
“Akanni, sôe o ti sôetan, sôe o ti mura, sôe ka maa woô ara wa loô sile ni, abi ko o maa lu mi loô,
emi ati eô la joô n pada loô sile, bi iyawo eô ko ba feô ariwo, tiwoô naa ko si feô esôu, nisôo niwaju
bayii ki n maa teôle oô.”
Emi sôeôsôeô dele ni, Seôki waa pade mi loôna, a waa duro si idi kanga, a joô n soôroô, afi bi mo sôe
reôni naa to yoô niwaju to n rin soôgu-soôgu, toju eô poôn kankan, to roju koko bii eôni ti woôn so pa.
Emi ti feôeô koôkoô pariwo, mo feôeô soô pe, “Baale wa ree o, eôni loô lo boô,≈ sôugboôn nigba ti mo roju
ara won
Te e ba reni to gbe
omburela nigba tojo o
ro, e yera fun un—
Fasola
Idibo 2015: Jonathan
ko lo maa dibo Kwara
o—Saraki
Oludije sipo gomina
ninu egbe APC atawon
meji mi-in n jejo esun
ipaniyan
Ala roye gba ami-eye
iwe iroyin to pegede
Kuolifaya idije Afrika:
Bi Eagles se le yege ree
o
E tun pade wa lori ero
E wa awon iroyin wa
Alaaji, nisôe ni mo yaa sinmi, oôroô oôloôroô ko ni i di temi lae. Eôyin ti mo tieô maa wo bayii, Iya Dele ni mo ri, lo
n boô fian fian, mo si mi ori mi bayii, ninu Alaaji ati obinrin yii, O·loôun ma jeô ko jeô pe eôni kan ni yoo pa eôni
kan, abi iru ki leleyii.
Awoôn mejeeji ko joô loô sibi kan naa o, onikaluku gba inu yara reô loô ni, Iya Dele loô si yara tieô, Alaaji naa gba
paloô loô, ko si duro ni paloô, o sa woônu yara loôhun-un loô ni. Woôn ko ki wa o, woôn ko soôroô seônikan ninu awa
mejeeji ta a duro, woôn kan n loô ni. Emi naa ko ki eônikan ninu woôn o, sôugboôn Seôki ki awoôn mejeeji, woôn ko si
da a lohun, oôroô naa le ju beôeô loô. Eyi to waa ya mi leônu ju ni taaroô oôjoô keji. Bi oôroô naa sôe sôeôleô, titi di bi mo ti n
wi yii, bii ala lo n joô loju mi. Ba a sôe n kirun asubaa tan bayii ni mo beôreô si i ri ero nile wa.
Latoôjoô tawoôn eôbi Alaaji ti n waa ba wa da soôroô ija, tabi ti woôn ti n waa sôe mitinni loôdoô wa, n ko ri i ki woôn
poô to beôeô yeôn ri. O feôreô jeô pe gbogbo awoôn ara Agege lo wa, awoôn ara Sôogunleô, baba woôn kan ti mo ti ri tipeô
ti woôn koôle si Sango, eôgboôn woôn kan to wa l’Abeôokuta, ati boôoôda to peô ni Ghana titi ko too di pe o pada wa
sile, latigba to si ti de ki i de oôdoô eônikan, Idi-Iroko ni woôn lo koôle si. Bi mo sôe ri gbogbo woôn bayii ni mo ti
moô pe biliisi ti sôeôleô, ko si seônikan to soô fun mi ti mo fi moô pe n ko gboôdoô gbe eôru mi ki n ni mo n loô si sôoôoôbu
kankan, mo duro jeôeô ni.
Nigba ti mo woônu paloô pe ki n loôoô ki woôn, eôru ba mi, gbogbo ibeô lo ti kun gidangidan, awoôn mi-in jokoo sileô
ninu woôn ni. Mo yaa ki woôn daadaa, beôeô ni mo n kunleô ti mo n dide, gbogbo woôn ni mo kunleô fun pata. Mo
waa loô ba Baba Agege, mo ni kin ni woôn feô, ki n loô si kisôinni bayii ki n beôreô si i se ounjeô woôn, mo ni woôn
gboôdoô jeôun nile mi laaaroô kutu. Baba dahun: ‘’Beôeô ni tieô ri, Suwee, bibiire ko sôee fowo ra. A ko le jeôun
leôeôseônyi, o digba yaa ba yanju oôroô yaa ba wa yii naa. Maa loô ni tireô, oômoô daadaa!’’ Mo yaa roôra jade jeôeô. Mo
pade Seôki loôna, mo soô fun un. Seôki ni, wahala wa o.

Documentos relacionados

Iya Dele ma n korin owe bu mi ninu ile o

Iya Dele ma n korin owe bu mi ninu ile o moôto loô niyi. Eôseô mi ni mo fi n rin. Bi mo sôe n rin faufau loô nijoô naa, beôeô ni mo gboô gboôngan leôyin mi, awoôn aladura ti woôn maa n lu aago kiri yeôn ni. Leôeôkoôoôkan beôeô, bi mo ba t...

Más detalles

Iyaale mi ti tun bere o, o fere bu mi pa

Iyaale mi ti tun bere o, o fere bu mi pa ko pe rara, oun ko moô bo sôe n sôe oun, ara oun n gbona, ori oun feôeô daru. Ni mo ba ni o daa nigba yeôn, ko loô si sôoôoôbu eô ko loôoô sinmi, bo ba deô sinmi tan ti ara reô ba baleô, yoo moô oh...

Más detalles

O ma se o: Bi aisan ito-suga se pa Iyalode Adunni Bankole

O ma se o: Bi aisan ito-suga se pa Iyalode Adunni Bankole tun moô si Iya rere. Bawoôn osôere sôe n banujeô lori isôeôleô oôhun lawoôn soôroôsoôroô ori redio ati teôlifisôan n soô pe iku to pa Iyalode ilu Gbagura yii ko sôe ohun rere. Lara awoôn agba soôro...

Más detalles