O ma se o: Bi aisan ito-suga se pa Iyalode Adunni Bankole

Transcripción

O ma se o: Bi aisan ito-suga se pa Iyalode Adunni Bankole
E ba wa dele
E mo nipa wa
ba wa sise Adiresi wa
E polowo oja yin
AKEDE Agbaye
Idanileko ALAROYE
O ma se o: Bi aisan ito-suga se pa Iyalode Adunni Bankole lojo
igbeyawo omo e ree
Bi o ba fe
Awon Iroyin to se koko
Ibo ku si dede: PDP
Taofik Afolabi
ipinle Ogun ko ti i mo
T
ibi ti won n lo
iti di asiko yii lawoôn eeyan sôi n daro iku ojiji to pa Iyalode Adunni Bankoôle tawoôn mi-in
tun moô si Iya rere. Bawoôn osôere sôe n banujeô lori isôeôleô oôhun lawoôn soôroôsoôroô ori redio ati
teôlifisôan n soô pe iku to pa Iyalode ilu Gbagura yii ko sôe ohun rere.
Lara awoôn agba soôroôsoôroô to fi eto eô keôdun iku areôwa obinrin yii ni oôga-agba ileesôeô radio
Faaji FM, O·joôgboôn Ambrose Oluyatoô Sôomide. Ohun ti oôkunrin naa soô ni pe oôpoô oore ni
mama to ku yii sôe fawoôn soôroôsoôroô, awoôn nnkan nla nla lo sôe fawoôn lasiko tawoôn feôeô sôayeôyeô
kan laipeô yii.
ALAROYE gboô pe loôjoô ti oômoô eô to sôegbeyawo loôjoô Abameôta, Satide, to koôja yii sôe moô-mi-nmoô-oô niluu Abeôokuta lobinrin naa sôubu lojiji, latigba naa laisan si ti da a gunleô. Nisôe lawoôn
moôleôbi eô n gbe e kiri lati doola eômi eô, sôugboôn lojiji niroyin iku eô ja lu awoôn eeyan laya ni
nnkan bii aago kan oôsan oôjoô Abameôta, Satide, to koôja pe Iyalode Adunni Bankoôle ti ku.
Awoôn to koôkoô gboô iroyin yii ko fi taratara gba a gboô, afigba ti woôn gboô leônu awoôn to sunmoô
oloye ilu Gbagura naa to tun jeô iyawo baba agbeônusoô ile igbimoô asôoju-sôofin teôleô, iyeôn Oloye
Alani Bankoôle.
Geôgeô bi ALAROYE sôe gboô, awoôn kan ni aisan oôkan lo n yoô obinrin areôwa naa leônu, beôeô
lawoôn mi-in soô pe itoô sôuga lo n sôe e. Sôugboôn ohun to daju ni pe o ti to oôjoô meôta ti aisan ti n
ba obinrin naa to ti figba kan sôe isôeô iroyin yii finra. Sôugboôn ni nnkan bii oôseô meji ni kinni
oôhun gba oôna to lagbara yoô, lati bii oôjoô marun-un seôyin lo si ti wa leôseô kan aye eôseô kan oôrun
nileewosan to ti n gba itoôju, ko si laju titi ti eôleômii fi gba a ni nnkan bii aago meôfa aaroô oôjoô
Satide to koôja.
Ohun to pa awoôn eeyan leôkun ninu iku areôwa obinrin naa ni pe oôjoô ti oômoô eô, Mopeloôla, feôeô
sôayeôyeô igbeyawo niku woôle weôreô to mu un loô. Bo tileô jeô pe iku eô ka awoôn eôbi eô lara, ko jeô ki
awoôn eeyan to wa sibi igbeyawo oômoô eô yii moô pe oôfoô nla sôeô woôn. Lati aaroô lawoôn abanisôe ti
woôn woô asôoô ankara eôgbeôjoôda ti woôn mu fun ayeôyeô oôhun ti n de gboôngan ti woôn ti sôayeôyeô
iyawo n'Ikeôja, niluu Eko.
Sôe lawoôn moôleôbi eô ti woôn ti gboô nipa isôeôleô aburu yii ko le soôroô jade pe iya oômoô tawoôn feôeô
sôegbeyawo eô ti ku, tawoôn mi-in si n doôgboôn soô oôroô iku obinrin naa labeônu laarin ara woôn.
Bakan naa la gboô pe peôlu ibinu lawoôn oôreô Iyalode Adunni fi kuro nibi ayeôyeô naa nigba ti
woôn gboô pe oôreô awoôn ti ku, sôe ni gbogbo woôn ba eôkun ati ibanujeô pada sinu moôto woôn, ti
woôn si n sunkun kikoro pe ki i sôe asiko yii lo yeô ki Iyalode ilu Gbagura naa ku.
O·koô, Oloye Alani Bankoôle ati oômoô orogun oloogbe, Amofin Dimeji Bankoôle, naa wa nibi
ayeôyeô naa, nisôe ni woôn sôoju furu bii eôni pe nnkan kan ko sôeôleô. Bo tileô jeô pe ohun tawoôn kan
soô ni pe ko yeô ki woôn sôe igbeyawo yii loôjoô naa, sôugboôn awoôn mi-in soô pe niwoôngba ti woôn ti
mu oôjoô, ti woôn si ti moô pe obinrin naa ti daku fun oôjoô marun-un, ohun to yeô ki woôn sôe naa ni
woôn ti sôe yeôn.
Ohun to sôe ni laaanu ju ni pe iya to bi obinrin gbajumoô yii wa nibi igbeyawo oômoôoômoô eô lai
moô pe oômoô oun ti ku. Gbogbo oôna ni awoôn eeyan gba lati ri i pe asôiri oôroô naa ko tu si i loôwoô
titi ti woôn fi pari eto.
Moôsôuari osôibitu ti gbajumoô ilu Eko naa ku si lo sôi wa digba ti a n ko iroyin yii joô, tawoôn
moôleôbi eô si ti n sôepade lori bi woôn yoo sôe sinku eô.
O·dun to koôja ni Iyalode Bankoôle sôayeôyeô oôdun karundinloôgoôta to dele aye, ko si ti i ju bii
oôdun meôrin loô to sôi ile eô tuntun to koô siluu Ikorodu. Oloye Olusôeôgun O·basanjoô lo ba a sôi ile
oôhun loôjoô naa.
Omoose gomina lu
osise abe re lalubami
l'Ondo
PDP nikan lo le mu
ayipada rere ba ipinle
Kwara—Ajibola
Mimiko yoo je ki PDP
fidi remi nipinle
Ondo—Olu Ogunye
Ibo gomina: Ajimobi pe
Ladoja, Akala si
iforowero ita gbangba
Agbaboolu Afrika: Ta
ni yoo di oba?
E tun pade wa lori ero
E wa awon iroyin wa
O·kan pataki ninu awoôn gbajumoô ilu to si gbafeô daadaa ni Iyalode Adunni Bankoôle, ko si osôere ti ko moô iya
yii, beôeô lawoôn olorin maa n ki i ninu awoôn reôkoôoôdu woôn

Documentos relacionados